

Amǫtękųn tira pka lāti mų Adááko.
Adááko sa asala lati ǫwǫ Amọtékun.
Ǫjǫ nko, Amọtékun kpe Adááko, "je ka je orę. Nkan tin iwon je, emi o kin je. Ko si nka ti o ma je ka di ota ara wa."
Adááko gba. Amọtékun wipe, "je ka mule bi ore. Ti kan nu wa ba dalę, ọmọ re a ku."
Won mu ibura lati je ore. Ni gba tio di ale, Adááko sun la be igi. Amọtékun sun leka igi loké.
Adááko wáá son rá. Amọtékun wa ti rin.
Amọtékun ni idanwo lati jẹ Adááko sanra. O wi fun ara rẹ pé, "Emi ko bikita nipa ibura naa. Emi ko kpáákpáá bi ọmọ!"
Amọtékun fo sile lati mu Adááko. Sugbon Ṣugbọn o rira re láárin awọn ẹka igi méji.
Oya Adááko lenu. O fo soké osi ké, "Beh! Beh!"
Amọtékun wa be ore mi. ore mi ran mi lowo. A mulę kpé eni tio ba dale bi ore, oma pada nu ọmọ rę."
Adaako da louu, "awon obi re ni o mule. Ni siyin o ti je ti re."

