Igi Alafia
Mpumelelo Mlangeni
Mpumelelo Mlangeni

ǫmǫ obirin kan wa ti oruko re nje Ayanda.

Ayanda je ǫmǫ kan soso a won obi re.

Iya ati baba re fe kǫ ara won silę.

1

Ayanda pkinu lati fi ilé silę.

Olo sinu aginju nitori ko mo ibomi to fe lǫ.

2

Ikooko ni nų aginju lé Ayanda, owa gųn ori igi.

Ikooko fe gé ję, lo wa gųn lo si oke sí.

3

Ni oke ori igi, Ayanda ri oorun tio lęwa.

O subu ni ife pelu oorun, owa pkinu lati gbé ninu aginju.

4

Ayanda gun ori igi lojojumo lati ba oorun sǫrǫ.

Oorun wa je idilé ę.

5

Ojo kan, Ayanda wa ri arakunrin kan ni abe igi.

Arakunrin na wa je baba re.

Ayanda bolę lori igi, baba re wa salayé idi tio fi wa bę.

6

Arakunri so wipke, ki won to bi e, emi ati iya re pkade ni bi yi. Oje ibi pkataki.

7

Ko pe ni iya Ayanda wa sinu aginju.

Owa lati ba Alafia pelu baba Ayanda.

Eyi ni igi Alafia won.

8
You are free to download, copy, translate or adapt this story and use the illustrations as long as you attribute in the following way:
Igi Alafia
Author - Mpumelelo Mlangeni, Tshiamo Msimanga, Tumi Mofokane
Translation - Bright Omonikhe, Francisca Ofodile, Oluwatosin Akobe, Taiye Abenu, Tony Okuagu
Illustration - Mpumelelo Mlangeni, Tshiamo Msimanga, Tumi Mofokane
Language - Yoruba
Level - First paragraphs