ìgbé ayé ni erée Bóòlù
Pimville Library Soccer
Pimville Library Soccer

Bling
jé olúfé erée boolu.


Ti
a ba nsoro nipa ere idaraya, a ma so wipe,
igbe aye ni ere boolu je.

1

Bling
je okan ninu awon akeko Oluko
Tsepo to dara ju.


Oluko naa fi awon
omo egbe re yangan, opolopo si fe darapo
mo won.

2

Ìdíje Pàtàkì ńbò lónà.


Àwon omo egbé sì ńgbáradì lójoójúmó.


Inú gbogbo won sìn
dùn fún ìdíje ńlá tó
ńbò!

3

Olùkó láti egbé alátakò, ó jé onílara okùnrin.


Ó
ńjowú àseyorií olùkó Tsepo.

4

Kó tó di ójǫ Ìdíje, Olùkó onílara
egbe alátakò lo sí orí pápá


Ó
sì gbin nkàn olóró


Ó
gbin umuthi!

5

 Bling fi ìtara bèrè eré idìjé
náà.


Ó
sáré láti gbá bóòlù wolé

6

Ó
kùnà, ó sì subú lulè.


“Bling?”
àwon ènìyàn paruwo


“Bling?”
Olùkó Tsepo bèbè.

7

“Kò sí ohun
tó le jámi kulè!” Bling bá ara rè sòrò.


“ìgbé ayé
ni erée bóòlù.”


Ó
dìde, ó sì díje parí.

8
You are free to download, copy, translate or adapt this story and use the illustrations as long as you attribute in the following way:
ìgbé ayé ni erée Bóòlù
Author - Pimville Library Soccer
Translation - Oluwatoyin Falana
Illustration - Pimville Library Soccer
Language - Yoruba
Level - First sentences