Ilé Luwo
Little Zebra Books
Jacob Matthess

Luwo lo sílé ìjósiǹ
pèlú iyá re.


ìyá re di owó re mú
lójú ònà

1

Nínú ilé ìjósiǹ,
awon èrò púpó péjò.


Won
nkorin

2

Luwo fi ilé ìjósiǹ
sílè.


ìyá re ko
ri.

3

Luwo dúró sójú ònà.


Ó
wo òjú ònà, ó ronú, “ilé mi da?”

4

Ó
gba ojú óná naa. Ó rí
ilé ńlá kan.


“Rárá o, ilé wá
kó nìyí. Ilé wa kéré.”

5

Luwo rìn síwájú díè si. Ó ri
ilé lórí òpó.


“Rárá o, ilé wá
kó nìyí, ilé wa kò
sí lórí òpó.”

6

Ó
si ǹtesíwájú. Ó rí ilé kékeré
tí a fi koríko Alámò kó.


“Rárá o, ilé wá
kó nìyí. Ilé wa ní
ogìri Alámò.”

7

Luwo rìn jìnnà.
Ó rí ilé kékeré tí igi
wa níwáju re.


“Rárá o, ilé wá
kó nìyí. Igi méjì ló
wà níwájú ilé wa.”

8

Nígbàtóyá Luwo ri ìyá re tó nbò
wá sódò re. Luwo sáré sii.


Iya re wípé, “jé
ká lo sílé!”

9

Ewo ni ilé Luwo?

10
You are free to download, copy, translate or adapt this story and use the illustrations as long as you attribute in the following way:
Ilé Luwo
Author - Little Zebra Books
Translation - Esther, Meweabi Chibuzor, Raji
Illustration - Jacob Matthess
Language - YORUBA
Level - First sentences