Mo Fẹ́ràn Kàwé
Letta Machoga
Wiehan de Jager

Mo fẹ́ràn kàwé.

1

Mo máa n kàwé pẹ̀lú ọ̀rẹ́ mi.

2

Olùkọ́ mi ń rán mi lọ́wọ́ láti kàwé.

3

Tani mo lè kàwé sí i?

4

Mo ń kàwé pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ mi.

5

Tani mo lè kàwé sí i?

6

Bàbá àti bàbá bàbá mi ń ṣiṣẹ́.

7

Tani mo lè kàwé sí i? Mo lè kàwé fúnara mi!

8
You are free to download, copy, translate or adapt this story and use the illustrations as long as you attribute in the following way:
Mo Fẹ́ràn Kàwé
Author - Letta Machoga
Translation - Blessing Williamson, Victor Williamson
Illustration - Wiehan de Jager, Vusi Malindi
Language - Yoruba
Level - First words