ìkókó àti ẹyẹ Àkọ̀
South African Folktale
Emily Berg

Àwọn òbí kan fí ọmọ ìkókó sílẹ́ nílé pẹ̀lú ọmọ wọn tí ó dàgbà jù

1

Ọmọ tí wọ́n fí ọmọ ìkókó ṣọ́ lọ ṣeré, ó sì gbágbé nípa ọmọ ìkókó.

2

Ní ọjọ́ kan, ẹyẹ àkọ̀ rí ọmọ ìkókó tí ó ń ké

3

Wọ́n gbé ọmọ náà jáde nínú aṣọ tí wọ́n fi bò ó, wọ́n sì fò lọ.

4

Ìyá ọmọ ìkókó náà rí àwọn ẹyẹ àkọ̀ mẹ́rin tí wọ́n ń fò lọ pẹ̀lú ọmọ rẹ̀

5

Àwọn ẹyẹ yìí tọ́jú ọmọ náà.

6

Nígbà tí àwọn ẹyẹ yìí kò sí nílé. ọ̀pọ̀lọ́ kan gbé ọmọ náà mì!

7

Ọ̀pọ̀lọ́ dá ọmọ ìkókó padà fún àwọn òbí rẹ̀ lẹ́yìn tí o gbe eṣinṣin mẹ́ta.

8
You are free to download, copy, translate or adapt this story and use the illustrations as long as you attribute in the following way:
ìkókó àti ẹyẹ Àkọ̀
Author - South African Folktale
Adaptation - Olusegun Soetan
Illustration - Emily Berg
Language - Yoruba
Level - First words