Òḿò ōbīrīń ati òmò ókúrí
GROO ADISA (VIDA)
Rob Owen

Iyatọ towa larín ọmọ ọkunrin-rin ati ọmọ obirin.

1

Ti wọn ba sẹsẹ bi ọmọ ọkunrin-rin adabi ike to fẹlẹ ti eniyan le tẹfọ lai lo agbara kankan lelori ti yofifọ pẹrẹpẹ itun- mọ re ni wipe koni agbara kankan lasiko naa tori awọn obi rẹ ni wọn o ma tọju rẹ lọ wọ ati pe ase wọn ni yo ma gba.

2
You are free to download, copy, translate or adapt this story and use the illustrations as long as you attribute in the following way:
Òḿò ōbīrīń ati òmò ókúrí
Author - GROO ADISA (VIDA)
Illustration - Rob Owen, Adonay Gebru
Language - Yoruba
Level - First paragraphs